W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo...

42
W302 Itsna olumulo This is the Internet version of the User guide. ' Print only for private use.

Transcript of W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo...

Page 1: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

W302

Itọsọna olumulo

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 2: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

2

A ki ọ ku oriire fun rira Sony Ericsson W302. Fun akoonu foonu ni afikun, lọ si www.sonyericsson.com/fun. Fi orukọ silẹ ni isiyi lati gba ibi itọju ori ayelujara ati ipese pataki ni www.sonyericsson.com/myphone. Fun atilẹyin ọja, lọ si www.sonyericsson.com/support.

Awọn aami titẹle ilanaAwọn wọnyi yoo han ninu Itọsọna olumulo yi: > Lo bọtini ašayan lati yi lọ ko si yan

Tẹ bọtini ašayan laarin

Tẹ bọtini lilọ kiri si oke

Tẹ bọtini lilọ kiri si isalẹ

Tẹ bọtini lilọ kiri si apa osi

Tẹ bọtini lilọ kiri si apa ọtun

Akọsilẹ

Italolobo

Ikilọ

Tọkasi wipe išẹ kan tabi išẹ jẹ nẹtiwọki- tabi igbẹkẹle šiše-alabapin. Gbogbo awọn akojọ ašayan tabi išẹ le ma wa ninu foonu rẹ. Kan si onišẹ nẹtiwọki rẹ fun alaye diẹ ẹ sii

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 3: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

3

Kaadi SIMKaadi (Subscriber Identity Module) SIM, ti o gba lati ọdọ onišẹ nẹtiwọki rẹ, ni alaye nipa šišẹ alabapin rẹ ninu. Paa foonu rẹ nigba gbogbo ki o si yọ šaja ati batiri na šaaju ki o to fi sii tabi yọọ kaadi SIM kuro.

Koodu PIN (kọkọrọ kaadi SIM)PIN (Personal Identification Number) koodu jẹ kọkọrọ kaadi SIM to daabobo šiše-alabapin rẹ, šugbọn kii še foonu funrararẹ. Ti kaadi ba ti wa ni titiipa, o ni lati tẹ koodu PIN sii nigba ti o tan-an foonu rẹ. Lati yi koodu PIN rẹ pada, wo Kọkọrọ kaadi SIM loju iwe 36.PIN oni-nọmba kọọkan yoo han bi *, ayafi ti o ba bẹẹrẹ pẹlu oni-nọmba pajawiri, fun apẹẹrẹ, 112 tabi 911. O le pe nọmba pajawiri laisi titẹ PIN sii.

O le fi awọn olubasọrọ pamọ sori kaadi SIM šaaju yiyọ kuro lati inu foonu rẹ. O tun le fi awọn olubasọrọ pamọ ni iranti foonu. Wo Awọn olubasọrọ loju iwe 27.

Ti o ba tẹ PIN ti ko tọ si ni igba mẹta ni ọna kana, Ti dina mö PIN yoo han. Lati sina fun, o nilo lati tẹ PUK (Personal Unblocking Key) rẹ sii.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 4: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

4

Ngba agbara si batiri

Batiri foonu ti gba agbara diẹ nigba ti o ra. Yoo gba to wakati 2,5 o pọju lati gba agbara si batiri ni kikun.

Lati gba agbara si batiri naa 1 So šaja pọ mọ foonu pẹlu aami agbara ori šaja ti nkọju si ọna

oke. Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara.

2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke.

Aami batiri loju iboju ko le han titi foonu yoo fi gba agbara fun ọgbọn išẹju 30.

O le lo foonu nigbati ngba agbara lọwọ. O le gba agbara si batiri diẹ ẹ sii tabi kere si wakati 2,5. Idilọwọ gbigba agbara ko le ba batiri jẹ.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 5: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

5

Memory Stick Micro™Foonu rẹ nše atilẹyin Memory Stick Micro™ (M2™). Kaadi iranti n fikun aye ibi ipamọ diẹ ẹ si foonu rẹ, fun orin, awọn ohun orin ipe, agekuru fidio, aworan ati bẹ bẹ lọ. O le pin alaye ti o fipamọ nipa gbigbe tabi didakọ rẹ si awọn ẹrọ ibaramu kaadi iranti miiran.

Lati fi Memory Stick Micro™ (M2™) sii• Šii ideri ki o fi kaadi iranti sii pẹlu awọn olubasọrọ ti nkọju si ọna

isalẹ.

Lati yöö Memory Stick Micro™ (M2™) kuro• Tẹ eti lati tusilẹ ati lati yọọ kuro.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 6: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

6

Ntan foonu naaLati tan-an foonu naa1 Tẹ mọlẹ .2 Tẹ PIN kaadi SIM rẹ sii, ti o ba

beere.3 Yan Bẹẹni lati lo ošo olušeto.

ImurasilẹLẹhin ti o titan foonu rẹ ti o si ti tẹ PIN rẹ sii, orukọ onišẹ yoo han loju-iboju. Eyi ni a npe ni imurasilẹ. O le še ati gba awọn ipe bayi.

Lati paa foonu naa• Tẹ mọlẹ .

Ti o ba ni ašiše nigba ti o n tẹ PIN rẹ sii, o le tẹ lati pa awọn nọmba rẹ lati oju iboju.

Ti foonu rẹ ba wa ni pipa fun rara ẹ nigba gbigbe, tan-an titipa bọtini aifọwọyi. Eyi yoo še idilọwọ awọn ohun kan ti o wa ninu apo tabi apamọwọ rẹ ni mimu bọtini tan/pa šišẹ lairotẹlẹ.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 7: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

7

Išẹ nẹtiwọki agbegbeAaye ifi nẹtiwọki han yoo fi agbara nẹtiwọki GSM han ni agbegbe rẹ. Lọ si ipo miiran ti o ba ni awọn išoro ipe ati išẹ nẹtiwọki agbegbe ti ko dara. Ko si nẹtiwọki tunmọ si pe o ko si ni ibiti o ti le ri nẹtiwọki.

Ipo batiri

= Išẹ nẹtiwọki agbegbe to dara

=Išẹ nẹtiwọki agbegbe aropin

= Batiri foonu naa ti gba agbara ni kikun

= Batiri foonu naa ti šofo

Ipo batiriIšẹ nẹtiwọki agbegbe

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 8: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

8

Awọn aami ibojuAwọn aami yi le han loju-iboju.

Aami Apejuwe

Ipe ti a padanu

Aimudani ti sopọ

Ti šeto foonu si ipalọlọ

Ti gba ifọrọranšẹ wọle

Ti gba ifiranšẹ alaworan wọle

Ti gba ifiranšẹ imeeli wọle

Titẹ ọrọ asọtẹlẹ sii ti wa ni mu šišẹ

Ti gba ifiranšẹ olohun wọle

Ipe ti nlọ lọwọ

Redio FM nšišẹ

Ti mu itaniji šišẹ

Ti mu išẹ Bluetooth šišẹ

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 9: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

9

Akopọ foonu

3

1

2 9

1 Agbọrọsọ eti

2 Bọtini Walkman

3 Iboju

4 Awọn bọtini ašayan

5 Bọtini ipe

6 Bọtini akojọ ašayan awọn ọna abuja

7Asopọ fun šaja, aimudani ati okun USB

8Bọtini lilọ kiri/Awọn išakoso ẹrọ orin Walkman

9Awọn bọtini iwọn didun/ Awọn bọtini sisun kamẹra

10 Bọtini Tan/Pa

11 Bọtini C (Ko o kuro)

12Bọtini kamẹra/Bọtini agbohunsilẹ fidio

13 Bọtini ipalọlọ

4

5

6

10

11

128

7

13

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 10: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

10

BọtiniLọ si akojọ ašayan akọkọ tabi yan awọn ohun kan

Yi laarin awọn akojọ ašayan ati taabu

Yan awọn ašayan to han lẹsẹkẹsẹ loke awọn bọtini lori iboju.Pa awọn ohun kan gẹgẹbi awọn aworan, ohun ati awọn olubasọrọ rẹ.

Šii ẹrọ orin Walkman™. Tẹ lati lọ laarin ẹrọ orin Walkman™ ati imurasilẹ.

Duro, sinmi ati šišẹ (bọtini orin). Tẹ lati dakẹjẹẹ tabi mu redio sọrọ. Tẹ soke tabi silẹ lati wa awọn ikanni titotẹlẹ.Rekọja orin išaaju nigbati lilo ẹro orin Walkman™. Lati wa awọn ikaani redio.

Rekọja orin išaaju nigba lilo ẹro orin Walkman™. Lati wa awọn ikaani redio.

Awọn ọna abuja mi – fi awọn išẹ ayanfẹ rẹ kun lati wọle si wọn yarayara

Kamẹra ati agbohunsilẹ fidio

Lati tan foonu si tan/pa a.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 11: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

11

Lilọ kiriAwọn akojọ ašayan akọkọ han bi awọn aami. Awọn eto ni akojọ ašayan miiran ni awọn taabu ninu.

Lati lilö kiri ni akojö ašayan akoko foonu1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn.2 Lo bọtini lilọ kiri lati gbe laarin awọn akojọ ašayan akọkọ.

Lati yi laarin awön taabu• Tẹ bọtini lilọ kiri ni apa osi tabi ọtun.

Lati lö sëhin ni ipele kan ninu akojö ašayan• Yan Pada.

Lati pada si imurasilë• Tẹ .

Lati tii bötini foonu pa• Tẹ mọlẹ .

Lati šii bötini foonu silë• Tẹ ko si yan Šii silẹ.

Lati šeto foonu si ipalölö• Tẹ mọlẹ .

Lati pe išë ifohunranšë rë• Tẹ mọlẹ .

Lati mu išë dopin• Tẹ .

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 12: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

12

Wo akojọ ašayan PlayNow™*

Ayelujara*Aaye akọọkan, Tẹ adirẹsi sii, Awn bukumaaki, Itan, Fi oju-iwe pamọ, Eto ayelujara

IdanilarayaAwọn eré, TrackID™, Fideo akorin, Igbasilẹ ohùn

Kamẹra

FifiranšẹKọ titun, Apo-iwọle, Imeeli, Akọpamọ, Apo-jijade, Ti firanšẹ, Ifohunranšẹ ipe, Awọn awoše, Eto

WALKMAN

Olusakoso faili**Gbogbo awn faili, Lori kaadi iranti, Ninu foonu

Awọn olubasọrọ Olubasọrọ titun

Redio

Awọn ipe**

Gbogbo ẹ Ti o tẹ Ti o padanu Ti o dahun

ỌganaisaItaniji, Awọn ohun elo, Kalẹnda, Awn. išẹ-šiše, Amušišẹpọ*, Aago, Aago išẹju-aaya, Ẹrọ-iširo

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 13: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

13

Eto**

GbogbogboAwọn profailiAago ati ọjọEde foonuAwọn ọna abujaIpo ofurufuAaboIpo foonuTun gbogbo rẹ to

Aw.ohun & titanjIwọn didn.oh.orinOhùn orin ipeIpo ipalọlọTitanij.pẹlu gbígb.Itaniji fun ifiranšẹDídún bọtini:

IfihanIšẹšọ ogiriAwọn akoriAwr ikini loju foon.Ipamọ ibojuImọlẹ

Awọn ipeŠiše ipe kiakiaDari ipeŠakoso awọn ipeAkoko ati iye owó*Fihan/tọju nọ. miAimudani

AsopọmọraBluetoothUSBAmušišẹpọ*Nẹtiwọki alagbekaEto ayelujara

* Diẹ ninu awọn akọjọ ašayan jẹ onišẹ, nẹtiwọki- ati šiše alabapin-ti o gbẹkẹle.** O le lo bọtini lilọ kiri lati yi lọ laarin awọn taabu inu awọn akojọ ašayan inu akojọ ašayan. Fun alaye diẹ ẹ sii, wo Lilọ kiri loju iwe 11.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 14: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

14

Walkman™ Ẹrọ orin Walkman™ jẹ orin tabi ẹrọ orin fidio. Awọn oriši faili to ni atilẹyin ni: MP3, MP4, 3GP, AAC, AMR, MIDI, IMY, EMY ati WAV (ošuwọn apẹẹrẹ o pọju 16 kHz). O tun le lo awọn faili sisanwọle to jẹ ibaramu 3GPP.

Ngbe orin lọ s'ibomiiO le gbe orin lati kọmputa rẹ si iranti foonu rẹ tabi Memory Stick Micro™ (M2™). Awọn ọna meji lo wa lati so foonu pọ mọ kọmputa: • lilo okun USB to ba foonu naa wa. • pẹlu asopọ Išẹ ọna alailowaya Bluetooth.O le fa faili ko mu silẹ laarin foonu rẹ ati kaadi iranti ati kọmputa kan ni Microsoft® Windows Explorer.

Lati so foonu pö mö kömputa nipa lilo okun USB1 Rii daju pe foonu rẹ ti wa ni tan-an.2 So okun USB pọ mọ foonu rẹ ati kọmputa naa.3 Foonu: yan Ibi ipamọ pupọ.4 Kọmputa: Duro fun awọn awakọ USB lati wa lori ẹrọ (tii še eyi

laifọwọyi). Ni igba akọkọ ti o so foonu rẹ pọ si kọmputa naa, o le nilo lati še idanimọ ati fun foonu lorukọ.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 15: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

15

Lati gbe awön faili ni ipo Ibi-itöju akopö1 So okun USB pọ mọ foonu ati kọmputa rẹ.2 Foonu: Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Eto > ni Asopọmọra

taabu > USB > Ibi ipamọ pupọ.3 Kọmputa: Duro titi iranti foonu ati kaadi iranti yoo han bi disk

ita gbangba ni Microsoft Windows Explorer.4 Kọmputa: Lori ori ikọwe kọmputa, tẹ lẹmeji Kọmputa mi aami.5 Kọmputa: Lati wo iranti foonu ati awọn folda kaadi iranti, tẹ aami

ti o še oniduro foonu rẹ lẹmeji labẹ Awọn ẹrọ to ni ibi-ipamọ ti o še kọọ kuro.

6 Daakọ ati lẹẹmọ faili rẹ, tabi fa ati ju silẹ, si sinu folda ti o fẹ lori kọmputa rẹ, ni iranti foonu rẹ tabi kaadi iranti rẹ.

Iranti foonu Kaadi iranti

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 16: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

16

Awọn akojọ orin Lati to awọn faili media ti a ti fipamọ si Olušakoso faili lẹsẹsẹ, o le šẹda awọn akojọ orin.

Lati šeda akojö orin 1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > WALKMAN > Aw. ašy.

> Orin mi > Aw. akjọ orn mi > Akj. orin titn. 2 Tẹ orukọ sii ko si yan O dara.3 Yi lọ si orin kikọ ki o si yan O dara.

Ma še yọọ okun USB kuro lati foonu tabi kọmputa nigbati gbigbe faili ba nlọ lọwọ eyi le ba iranti foonu ati kaadi iranti jẹ. O ko ni afani lati wo gbigbe faili ninu foonu rẹ titi ti o ba ti yọ okun USB kuro ninu foonu rẹ.

Fun gige asopọ okun USB lailewu ninu ipo Gbigbe faili, titẹ-ọtun ninu aami Disk yiyọ kuro ni Windows Explorer ko si yan Kọ.

Alaye diẹ ẹ sii nipa gbigbe awọn faili si foonu Walkman™ rẹ wa ni www.sonyericsson.com/support.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 17: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

17

Lati fi awön faili kun akojö orin 1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > WALKMAN > Aw. ašy.

> Orin mi > Aw. akjọ orn mi. 2 Yi lọ si akojọ orin ko si yan Ši i > Aw. ašy. > Fi media kun.3 Yi lọ si orin kikọ ki o si yan O dara.

Lati yö awön faili kuro lati akojö orin 1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > WALKMAN > Aw. ašy.

> Orin mi > Aw. akjọ orn mi.2 Yi lọ si ko si yan akojọ orin, lẹhinna yan Ši i.3 Yan faili naa ko si tẹ Aw. ašy. > Paarẹ > Bẹẹni.

Awön öna pupö lo wa lati še išakoso ërö orin Walkman™:• Tẹ tlati šii tabi gbe ẹrọ orin Walkman™ sẹgbẹ nigba

šišẹsẹhin.• Tẹ lati lọ si faili orin ekeji.• Tẹ lati lọ si faili orin to šaaju.• Tẹ mọlẹ tabi yiyara siwaju tabi sẹhin nigbati awọn faili

orin nšišẹ.• Tẹ tabi lati wo yi lọ awọn faili ni akojọ orin ti isiyi nigba

šišẹsẹhin.• Tẹ lati yan faili ti a fa ila si ninu akojọ.• Nigba šišẹsẹhin, tẹ Pada lati lọ si akojọ ašayan akọkọ.• Tẹ mọlẹ lati jade.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 18: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

18

Lati mu orin dun1 Lati imurasilẹ tẹ .2 Lọ kiri lori ayelujara fun awọn orin nipasẹ olorin, orin, tabi ninu

awọn akojọ orin. Yi lọ si akojọ ko si yan Ši i.3 Yi lọ si akọle yan Šišẹ.

PlayNow™Pẹlu PlayNow o le še awotẹlẹ, ra ati gbaa orin lati ayelujara nipasẹ Ayelujara. O le wa PlayNow ni Akj ašyn > PlayNow™.

TrackID™TrackID™ jẹ orin ti idanimọ išẹ. O le wa awọn akọle orin ri, awọn ošere ati orukọ awo-orin.

Lati wa alaye orin1 Nigbati o ba tẹtisi orin yi nipaše agbohunsoke, lati imurasilẹ

yan Akj ašyn > Idanilaraya > TrackID™ > Bẹrẹ.2 Nigbati redio ba nšišẹ yan Aw. ašy. > TrackID™.

O nilo bibamu eto Ayelujara ninu foonu rẹ. Wo Ayelujara loju iwe 32.

O nilo bibamu eto Ayelujara ninu foonu rẹ. Wo Ayelujara loju iwe 32.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 19: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

19

Redio

Lati tëtisi rëdio1 So aimudani pọ mọ foonu.2 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Redio.

Lati šakoso redio• Tẹ tabi lati wa awọn ikanni redio FM.

Lati fi ikanni redio FM pamö• Yan Aw. ašy. > Fipamọ.• Yi lọ si ipo kan ko si tẹ Yan.

Lati tëtisi ikanni rëdio FM ti o fipamö• Nigbati redio FM ba wa ni titan, tẹ – .

Lati jade kuro ni redio FM1 Yan Pada tabi tẹ .2 Gbe redio sẹgbẹ bi? han. Yan Bẹẹkọ.

Lati fi redio FM pa nigbati o ti gbe sëgbë1 Yan Akj ašyn > Redio.2 Yan Pada tabi tẹ .3 Gbe redio sẹgbẹ bi? han. Yan Bẹẹkọ.

Lati wo awön ašayan redio FM • Nigbati redio FM titan, yan Aw. ašy.

Maše lo foonu rẹ bi redio ni awọn aye a ti ka lewọ.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 20: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

20

Aworan Kamẹra ati agbohunsilẹ fidioO le ya awọn aworan ko si gba awọn agekuru fidio silẹ lati wo, fipamọ tabi firanšẹ. O le wa awọn aworan ti o fipamọ ati awọn agekuru fidio ni Akj ašyn > Olusakoso faili > Alibọọmu kamẹra.

Lati ya aworan1 Tẹ mọlẹ lati mu kamẹra šišẹ. 2 Tẹ tabi yi lọ si .3 Tẹ lati ya aworan. Aworan ti wa ni fipamọ laifọwọyi lori

kaadi iranti, ti o ba ti fii kaadi iranti sii. Bi kii ba še bẹ, aworan ti wa ni fipamọ ni iranti foonu.

Ma še šee igbasilẹ pẹlu imọlẹ ina to lagbara ni aaye ẹhin.

Lati yago fun aworan to ni abawọn, lo atilẹyin kan tabi aago ara-ẹni.

1

2

1 Sun sinu tabi sita

2 Ya awọn aworan/Gba fidio silẹ

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 21: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

21

Lati gba agekuru fidio silë1 Tẹ mọlẹ lati mu kamẹra šišẹ.2 Tẹ tabi lati yi lọ si .3 Tẹ Tẹ ni kikun si isalẹ lati bere gbigba silẹ. Agekuru fidio

ti wa ni fipamọ laifọwọyi lori kaadi iranti, ti o ba ti fi kaadi iranti sii. Bi kii ba še bẹ, agekuru fidio ti wa ni fipamọ ni iranti foonu.

Lati da ngbasilë duro• Tẹ . Agekuru fidio ti wa ni ipamọ laifọwọyi sori kaadi iranti.

Lati sun-un sinu tabi sita• Tẹ bọtini iwọn didun sokẹ tabi isalẹ.

Lati gbe awọn aworan si ati lati kọmputa rẹO le lo išẹ-ọna ẹrọ alailowaya Bluetooth™ ati okun USB lati gbe awọn aworan ati agekuru fidio laarin kọmputa ati foonu rẹ. Wo Bluetooth™ loju iwe 30 ati Lati gbe awọn faili ni ipo Ibi-itọju akopọ loju iwe 15 Fun alaye diẹ ẹ sii.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 22: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

22

NpeO gbọdọ tan foonu ki o si wa nibiti a ti le ri nẹtiwọki.

Lati še ipe1 Lati imurasilẹ tẹ nọmba foonu (pẹlu koodu pipe ilu-okeere ati

koodu agbegbe, ti o ba wa).2 Tẹ .

Lati mu ipe dopin• Tẹ .

Lati dahun ipe kan• Tẹ .

Lati kö ipe • Tẹ .

Lati yi iwön didun agbörösö eti pada nigba ipe• Tẹ bọtini iwọn didun soke tabi isalẹ.

Lati fi ërö agbohunsoke si titan nigba ipe• Yan Agrs.tn.

O le pe awọn nọmba lati awọn olubasọrọ rẹ ati akojọ ipe. Wo Awọn olubasọrọ loju iwe 27, ati Akojọ ipe loju iwe 23.

Ma še gbe foonu si eti nigbati o ba nlo agbohunsoke. O le ba igbọran rẹ jẹ.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 23: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

23

Lati še awön ipe si ilu okeere1 Lati imurasilẹ tẹ mọlẹ titi aami + yoo han loju iboju.2 Tẹ koodu orilẹ-ede sii, koodu agbegbe (lai si oodo akọkọ)

pẹlu nọmba foonu.3 Tẹ .

Lati wo awön ipe ti o padanu lati imurasilë• Nigbati Awọn ipe ti o padanu: ti han, yan Wo. Lati pe pada

yi lọ si nọmba naa ko si tẹ .

Akojọ ipeO le wo alaye nipa awọn ipe to šẹšẹ še.

Lati pe nömba kan lati inu akojö ipe1 Lati imurasilẹ tẹ .2 Yi lọ si orukọ tabi nọmba ki o tẹ .

Lati pa nömba kan rë lati inu akojö ipe1 Lati imurasilẹ tẹ .2 Yi lọ si orukọ tabi nọmba ko si yan > Bẹẹni.

Titẹ kiakiaTitẹ kiakia yoo jẹ ki o yan awọn olubasọrọ mẹsan ti o le tẹ yarayara. Awọn olubasọrọ le wa ni fipamọ ni awọn ipo 2-9.

Šeto ipo 1 si nọmba ifohunranšẹ naa.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 24: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

24

Lati fikun awön olubasörö si awön nömba šiše ipe kiakia1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Eto > ni Awọn ipe taabu

> Šiše ipe kiakia.2 Yan nọmba ipo ko si tẹ .3 Tẹ nọmba sii tabi yan Awọn olubasọrọ > O dara.4 Yi lọ si yiyan ko si yan O dara > O dara

Lati titë kiakia• Lati imurasilẹ tẹ nọmba ipo mọlẹ.

Awọn ipe pajawiriFoonu rẹ še atilẹyin fun pipe awọn nọmba pajawiri ilu-okẹẹrẹ, fun apẹẹrẹ, 112 ati 911. Awọn nọmba yi še lo deede lati še awọn ipe pajawiri ni eyikeyi orile-ede, pẹlu tabi laisi kaadi SIM ti a fi sii, ti nẹtiwọki GSM ba wa ni ibiti a ti le ri.

Lati še ipe pajawiri• Lati imurasilẹ tẹ nọmba pajawiri ti ilu-okeere, fun apẹẹrẹ, 112

ko si tẹ .

Ni awọn orilẹ-ede mii,awọn nọmba pajawiri miiran le tun ti ni igbega. Onišẹ nẹtiwọki rẹ le ti fipamọ awọn nọmba pajawiri ti agbegbe ni afikun lori kaadi SIM rẹ.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 25: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

25

FifiranšẹAwọn ifọrọranšẹ (SMS)O gbọdọ ni nọmba ile-išẹ ifiranšẹ, eyiti olupese išẹ rẹ ti pese ti o wa ni fipamọ lori kaadi SIM. O le ni lati tẹ nọmba na si funrara rẹ.

Lati kö ati iföröranšë1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Fifiranšẹ > Kọ titun

> Ifọrọranšẹ.2 Kọ ifiranšẹ ko si yan Tesi.3 Yan ašayan.4 Yan O dara > Firanšẹ.

Lati wo awön iföröranšë ti nwöle1 Ifiranšẹ titun lati: han. Yan Wo o. 2 Yan ifiranšẹ aika.

Lati wo awön ifiranšë ti wa ni ipamö ninu apo-iwöle.• Yan Akj ašyn > Fifiranšẹ > Apo-iwọle.

Lati gba ipo ifijišë ifiranšë 1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Fifiranšẹ > Eto > Ifọrọranšẹ

> Ìjábõ ifijišẹ.2 Yan Tan. Iwọ yoo gba ifitonileti nigbati ifiranšẹ ba ti wa ni ifijišẹ

daradara.

Rii daju pe oni ipa išẹ nọmba arin ninu foonu rẹ.

Wo Ntẹ ọrọ sii loju iwe 33.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 26: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

26

Awọn ifiranšẹ alaworan (MMS)Awọn ifiranšẹ alaworan le ni išẹ ọrọ, ohun ati awọn aworan. Ti fi wọn ranšẹ nipa lilo MMS si foonu alagbeka. O nilo bibamu eto Ayelujara ninu foonu rẹ. Wo Ayelujara loju iwe 32.

Lati sëda ifiranšë alaworan 1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Fifiranšẹ > Kọ titun

> Ifiranšẹ aworan.2 Yan ašayan lati šẹda firanšẹ naa.

Lati ranšë ifiranšë alaworan 1 Nigbati ifiranšẹ ba šetan, yan Tesi.2 Yan ašayan.3 Yan O dara > Firanšẹ.

Olufiranšẹ ati olugba o ti ni awọn iše alabapin to nše atilẹyin fifiranšẹ alaworan. Rii daju pe alabapin foonu ti še awọn atilẹyin gbigbe data, ati paapaa eto to tọ ninu foonu rẹ.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 27: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

27

Awọn olubasọrọO le fi awọn olubasọrọ pamọ sinu iranti foonu tabi SIM kaadi. O le da awọn olubasọrọ kọ lati iranti foonu lọ si kaadi SIM tabi lati kaadi SIM lọ si iranti foonu.

Awọn olubasọrọ aiyipadaO le yan iru alaye olubasọrọ ewo ni yoo han bi aiyipada. Ti o ba ti yan Awọn olubasọrọ foonu bi aiyipada, awọn olubasọrọ rẹ yoo fi gbogbo alaye ti o ti fipamọ ni Awọn olubasọrọ han. Ti o ba yan awọn olubasọrọ SIM bi aiyipada, awọn olubasọrọ rẹ yoo fi awọn orukọ ati nọmba ti o ti fipamọ sori kaadi SIM han.

Lati yan awön olubasörö aiyipada1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Awọn olubasọrọ > Aw. ašy.

> To ti ni ilọsiwaju > Aw.olubasọrọ aypd.2 Yan ašayan.

Wo Ntẹ ọrọ sii loju iwe 33.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 28: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

28

Awọn olubasọrọ foonuAwọn olubasọrọ foonu le ni awọn orukọ ninu, awọn nọmba foonu ati alaye ara ẹni. Wọn ti wa ni fipamọ ni iranti foonu.

Lati fikun olubasörö foonu1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Awọn olubasọrọ

> Olubasọrọ titun.2 Yi lọ si Orukọ idile: yan Fikun.3 Tẹ orukọ sii ki o si yan O dara.4 Yi lọ si Orukọ abisọ: yan Fikun.5 Tẹ orukọ sii ki o si yan O dara.6 Yi lọ si Nọmba titun: yan Fikun.7 Tẹ nọmba naa ko si yan O dara.8 Yan Fipamọ.

Lati pe olubasörö1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Awọn olubasọrọ.2 Yi lọ si, tabi tẹ awọn lẹta diẹ akọkọ ti, olubasọrọ sii.3 Tẹ .

Lati šatunkö olubasörö kan1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Awọn olubasọrọ. 2 Yan olubasọrọ kan.3 Yan Aw. ašy. > Šatnkọ olubsọrọ.4 Šatunkọ alaye ko si yan Fipamọ.

Tẹ aamin + ati koodu orilẹ-ede sii pẹlu gbogbo awọn nọmba iwe foonu. Lẹhinna o le lo wọn lẹhin-odi tabi ni ile. Wo Lati še awọn ipe si ilu okeere loju iwe 23.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 29: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

29

Lati pa olubasörö rë1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Awọn olubasọrọ. 2 Yan olubasọrọ kan.3 Yan Aw. ašy. > Paarẹ.

Lati da olubasörö kö si kaadi SIM1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Awọn olubasọrọ.2 Yi lọ si olubasọrọ.3 Yan Aw. ašy. > Die e sii > Daakọ si SIM.

Lati wo nömba foonu ti ara rë• Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Awọn olubasọrọ > Aw. ašy.

> Awọn nọmba mi.

Iranti awọn olubasọrọNọmba awọn akọsilẹ ti o le fipamọ si Awọn olubasọrọ da lori agbara kaadi SIM rẹ.

Lati šayëwo Ipo iranti awön olubasörö• Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Awọn olubasọrọ > Aw. ašy.

> Ipo iranti.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 30: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

30

Bluetooth™Išẹ ọna ẹrọ alailowaya Bluetooth™ nše asopọ alailowaya si awọn ẹrọ Bluetooth miiran, fun apẹẹrẹ, agbekọri Bluetooth. O le sopọ mọ awọn ẹrọ pupọ nigbakanna tabi še pašipaarọ awọn ohun kan.

Lati tan isë Bluetooth si titan-an• Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Eto > ni Asopọmọra taabu

> Bluetooth > Tan-an.

Lati fihan tabi töju foonu rë• Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Eto > ni Asopọmọra taabu

> Bluetooth > Hihan > Fi foonu han tabi Tọju foonu.

A še išeduro o pọju aaye laarin awọn ẹrọ Bluetooth meji si mita 10 (ẹsẹ 33), ti ko si ohun kan to lagbara laarin wọn.

Šayẹwo boya awọn ofin agbegbe tabi ilana fun lilo Išẹ-ọna ẹrọ Bluetooth alailowaya ni ihamọ. Ti ko ba gba laaye, o gbọdọ rii daju wipe išẹ Bluetooth wa ni pipa.

Ti foonu ko ba šee wa-ri fun awọn ẹrọ miiran ti nlo išẹ-ọna ẹrọ alailowaya Bluetooth tan isẹ Bluetooth si titan-an. Rii daju pe o šeto hihan si fi foonu han. Ti o ba šeto foonu si fipamọ, awọn ẹrọ miiran ti nlo išẹ-ọna ẹrọ alailowaya Bluetooth ko le še idanimọ rẹ.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 31: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

31

Lati ko ërö pö mö foonu rë1 Lati wa awọn ẹrọ to wa, lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Eto > ni

Asopọmọra taabu > Bluetooth > Awọn ẹrọ mi > Ẹrọ titun. 2 Yan ẹrọ kan lati inu akojọ. 3 Tẹ koodu iwọle si, ti o ba beere fun.

Lati ko foonu rë pö mö aimudani Bluetooth kan1 Lati wa awọn ẹrọ aimudani to wa, lati imurasilẹ yan Akj ašyn

> Eto > ni Asopọmọra taabu > Bluetooth > Awọn ẹrọ mi > Ẹrọ titun.

2 Yi lọ si ẹrọ aimudani ko si yan Bẹẹni.3 Tẹ koodu iwọle si, ti o ba beere fun.

Lati gba ohun kan wöle1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Eto > ni Asopọmọra taabu

> Bluetooth > Tan-an.2 Nigbati o ba gba ohun kan, tẹle awọn itọnisọna to han.

Lati fi ohun kan ti nlo Bluetooth ranšë 1 Lati imurasilẹ yan, fun apẹẹrẹ, Akj ašyn > Olusakoso faili

> Alibọọmu kamẹra.2 Yi lọ si aworan ko si yan Aw. ašy. > Firanšẹ > Bluetooth.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 32: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

32

AyelujaraO nilo eto Ayelujara to tọ ninu foonu rẹ. Ti eto naa ko ba si ninu foonu rẹ, o le:• Ri gba ninu ifọrọranšẹ lati ọdọ onišẹ nẹtiwọki.• Lori kọmputa kan, lọ si www.sonyericsson.com/support

beere ifọrọranšẹ pẹlu eto.

Lati yan profaili Ayelujara1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Ayelujara > Eto ayelujara

> Awọn iroyin. 2 Yan iroyin.

Lati bërë lilö kiri ayelujara1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Ayelujara. 2 Yan ašayan:• Aaye akọọkan – lọ si aaye akọọkan ti a yan tẹlẹ.• Tẹ adirẹsi sii – tẹ Adirẹsi ayelujara sii.• Awn bukumaaki – lọ taara si Adirẹsi ayelujara ti o fipamọ.• Itan – fi awọn oju-iwe ti o ti wo šaaju han.• Fi oju-iwe pamọ – lọ taara si Oju-iwe ayelujara ti o fipamọ.• Eto ayelujara – syan awọn ašayan gẹgẹbi awọn iroyin, akoko

asopọ, akojọ funfun.Lati da lilö kiri ayelujara duro• Nigba lilọ kiri lori ayelujara, tẹ mọlẹ .

Rii daju pe o ni šišẹ-alabapin foonu to nše atilẹyin gbigbe data ninu foonu rẹ.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 33: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

33

Awọn išẹ diẹ ẹAwọn ọna abujaAkojọ ašayan ọna abuja yoo fun ọ ni wiwọle yara yara si awọn išẹ.

Lati šii akojö ašayan öna abuja • Tẹ .

Ntẹ ọrọ sii Ọna meji ni o le lo lati tẹ ọrọ sii: multitap tabi titẹ ọrọ asọtẹlẹ sii.

Lati të örö nipa lilo titë örö asötëlë sii1 Fun apẹẹrẹ, lati kọ ọrọ bi “Jane”, tẹ , , , .2 O ni awọn ašayan pupọ bayi:• Ti ọrọ ti o han ba jẹ eyi ti o nfẹ, tẹ lati gba ko si fi aaye kun.

Lati gba ọrọ lai fi aaye kun, tẹ . • Ti o ba jẹ ọrọ ti o fẹ kọ lo yọju, tẹ tabi wa ka tun yẹ wọ

bọya ọrọ miran wa. Lati gba ọrọ ki o fi aaye kun, tẹ .• Lati tẹ aami iduro ati aami idẹsẹ sii, yan lẹhinna tabi

leralera.

Nipasẹ lilo titẹ ọrọ asọtẹlẹ sii o ni lati tẹ bọtini kọọkan lẹẹkan. Tẹsiwaju nipa kikọ ọrọ kan paapa ti o ba han bi išina. Foonu naa nlo iwe-itumọ lati ranti ọrọ naa nigbati o ti tẹ gbogbo awọn lẹta sii.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 34: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

34

Lati të örö lilo multitap sii• Tẹ – titi di gba ti ohun kikọ silẹ to fẹ yoo han.• Tẹ lati fi aaye kan kun.• Tẹ lati tẹ aami iduro ati aami idẹsẹ sii.• Tẹ lati yipada laarin awọn lẹta nla ati kekere.• Tẹ mọlẹ – lati tẹ awọn nọmba sii.

Lati yi öna kikösilë naa pada• Nigbati o ba kọ ifiranšẹ, tẹ mọlẹ .

Lati fi awön ohun kan kun iföröranšë• Nigbati o ba ko ifiranšẹ, yan Aw. ašy. > Fi ohun kan sii.• Yan ašayan.

Lati pa ohun kikö silë rë• Yan .

Lati yi ede kikö pada• Nigbati o ba kọ ifiranšẹ, tẹ mọlẹ .

Titi bọtini pa laifọwọyiBọtini foonu ti wa ni titiipa lẹhin igba diẹ.

Lati tan-an titiipa bötini laiföwöyi• Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Eto > ni Gbogbogbo taabu

> Aabo > Titipa bọt. aifọw. > Tan.

Awọn ipe si awọn nọmba pajawiri ilu okeere 112 si le šee še, paapaa ti bọtini foonu wa ni titi pa.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 35: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

35

IfohunranšẹOlupe le fi ifiranšẹ ifohunranšẹ silẹ nigbati o ko le dahun. O le gba nọmba ifohunranšẹ rẹ lati ọdọ onišẹ nẹtiwọki rẹ.

Lati të nömba ifohunranšë sii1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Fifiranšẹ > Eto > Nọmba

ifohùnrnš.2 Yi lọ si nọmba ifohunranšẹ naa ko si yan O dara.3 Tẹ nọmba ifohunranšẹ ti o gba lati ọdọ olupese išẹ rẹ sii ko

si tẹ O dara.

Lati pe išë ifohunranšë rë• Lati imurasilẹ tẹ mọlẹ .

Flight modeNi Ipo ofurufu netiwoki ati redio transceivers wa ni paa lati se aabo fun idamu si awọn eroja. Nigbati flight mode ti wa ni mu šišẹ, o beere lọwọ rẹ lati yan ipo nigbamii ti o ba tan foonu rẹ:• Deede – išẹ ni kikun.• Ipo ofurufu – išẹ die e. Ẹrọ orin Walkman™ nikan:

Lati mu akojö ašayan flight mode šišë• Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Eto > ni Gbogbogbo taabu

> Ipo ofurufu > Fihan ni bẹrẹ.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 36: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

36

Kọkọrọ kaadi SIMPIN ati PUK rẹ wa lati ọdọ onišẹ nẹtiwọki rẹ.

Lati šina fun kaadi SIM rë1 Nigbati Ti dina mọ PIN ti han, yan Šii silẹ2 Tẹ PUK rẹ sii ko si yan O dara.3 Tẹ PIN titun sii ko si yan O dara.4 Lati jẹrisi, tun PIN titun tẹ sii ko si yan O dara.

Lati tan-an kökörö kaadi SIM 1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Eto > ni Gbogbogbo

taabu > Aabo > Awọn titipa > Idaabobo SIM > Idaabobo.

2 Tun PIN rẹ tẹ sii ko si yan O dara.3 Yan Tan.

Lati šatunkö PIN rë1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Eto > ni Gbogbogbo

taabu > Aabo > Awọn titipa > Idaabobo SIM > Yi PIN pada.

2 Tun PIN rẹ tẹ sii ko si yan O dara.3 Tẹ PIN titun sii ko si yan O dara.4 Lati jẹrisi, tun PIN titun tẹ sii ko si yan O dara.

Ti ifiranšẹ PIN ti ko tö Iye igbiyanju ti o ku: ba han nigbati o šatunkọ PIN rẹ, o ti tẹ PIN tabi PIN2 lọna ti ko tọ sii.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 37: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

37

Titiipa foonu Titiipa foonu še idaabobo fun foonu lati yago fun lilo laigba ašẹ. O le yi koodu titi foonu pa pada (0000 nipa aiyipada) si eyikeyi koodu oni-nọmba mẹrin.

Lati šatunkö koodu titiipa foonu 1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Eto > ni Gbogbogbo

taabu > Aabo > Awọn titipa > Idaabobo foonu > Yi koodu pada.

2 Tẹ koodu ti isiyi sii ko si yan O dara.3 Tẹ koodu titun kan sii ko si yan O dara.4 Lati jẹrisi, tun koodu titun tẹ sii ko si yan O dara.

Lati šii foonu silë1 Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Eto > ni Gbogbogbo

taabu > Aabo > Awọn titipa > Idaabobo foonu > Koodu wo.

2 Tẹ koodu titiipa foonu rẹ sii ko si yan O dara.3 Yan Pa a.

TI o ba šeto idaabobo foonu si Pa a, iwọ ko nilo lati tẹ koodu titiipa foonu sii ayafi ti o ba ti fi oriši kaadi SIM sii foonu.

Ti o ba gbagbe koodu titun rẹ naa, o ni lati mu foonu rẹ naa lọ si ọdọ alagbata Sony Ericsson ti agbegbe rẹ.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 38: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

38

Titunto si ipilẹTi o ba ni išoro pẹlu foonu rẹ, gẹgẹbi baibai iboju, didi iboju, tati awọn išoro lilọ kiri, o yẹ ki o tun foonu naa to.

Lati tun foonu to• Lati imurasilẹ yan Akj ašyn > Eto > ni Gbogbogbo

taabu > Tun gbogbo rẹ to > Tesi. > Tesi.

Tun gbogbo rë to npa gbogbo olumulo rẹ gẹgẹbi awọn olubasọrọ, ifiranšẹ, aworan ati ohun ninu foonu rẹ.

Tun foonu rẹ bẹrẹ ni ojojumọ lati jẹ ki iranti šofo. Še titunto si ipilẹ ti o ba ni awọn išoro pẹlu agbara iranti tabi foonu nšišẹ laiyara.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 39: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

39

Aami Idanimọ ọtadidan, PlayNow ati TrackID jẹ awọn aami-išowo tabi aami-išowo ti a forukọ silẹ fun ni Sony Ericsson Mobile Communications AB. Sony, M2, Memory Stick Micro, ati WALKMAN jẹ aami-išowo tabi aami-išowo ti a forukọsilẹ ni Sony Corporation. Ericsson jẹ aami-išowo tabi aami-išowo ti a forukọsilẹ ti Telefonaktiebolaget LM Ericsson. Gbogbo awọn aami-išowo miiran jẹ ohun-ini awọn oniwun wọn. Ti ni iwe-ašẹ išẹ ọna ayipada ohun MPEG Layer-3 lati ọdọ Fraunhofer IIS ati Thomson.

Awọn Ilana ifiranšẹ si ilẹ okeere: Ọja yi, pẹlu software tabi data išẹ ọna eyikeyi ti o wa ninu rẹ tabi ti o ba ọja na de, le jẹ ohun ti a sọrọ le lori ni awọn ofin išakoso ifiranšẹ si ilẹ okeere ti orilẹ AMẸRIKA, pẹlu Ofin Abojuto Ifiranšẹ si ilẹ okeere ati awọn ilana ti o somọ ati awọn eto iyọọda ti orilẹ AMẸRIKA nipasẹ abojuto Išakoso Ohun-ini Ajeji ti Apakan Yara-išẹ Išuna ti orilẹ AMẸRIKA, o le jẹ afikun ohun ti a sọrọ le lori si awọn ilana ifi ọja ranšẹ tabi gbe wọle lati ilu okeere ni awọn orilẹ-ede miiran. Olumulo ati eyikeyi olohun-ini ọja gba lati ni ibamu to le pẹlu gbogbo iru awọn ilana ati gbigba wipe išeduro wọn ni lati gba eyikeyi iwe-ašẹ ti a beere lati fi ọja ranšẹ si ilu okeere, tun-fi ranšẹ, tabi gbe ọja yi wọle lati ilu okeere. Laisi iwọn ọja yi, pẹlu software eyikeyi ti o wa ninu rẹ, le ma še gbaa lati ayelujara, tabi bibẹkọ ti firanšẹ si ilu okeere tabi tun firanšẹ (i) sinu, tabi si ti orilẹ-ede tabi olugbe ti, tabi nkankan ni, orilẹ Kuba, Iraaki, Iraani, Ariwa Koria, Sudaanu, Siria (bi iru akojọ le šee tunwo lati igba de igba) tabi orilẹ-ede eyikeyi si eyiti orilẹ AMẸRIKA ti ni awọn ẹru ifi ofin de mọlẹ; tabi (ii) si ẹnikẹni tabi nkankan lori akojọ Apakan Išura orilẹ AMẸRIKA fun Awọn olugbe Pataki ti a Yan tabi (iii) ẹnikẹni tabi nkankan lori akojọ idinamọ ifiranšẹ si ilu okeere eyikeyi miiran ti o le muduro lati igba de igba nipasẹ Ijọba orilẹ AMẸRIKA, pẹlu šugbọn ko ni iwọn si Apakan Išowo ti Akojọ Eniyan ti a Kọ ti orilẹ AMẸRIKA tabi Akojọ Nkankan, tabi Apakan Ipinlẹ Akojọ Iyọọda Ti ko ni idagbasoke kiakia.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 40: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

40

Declaration of conformity for W302

We, Sony Ericsson Mobile Communications AB of Nya VattentornetSE-221 88 Lund, Swedendeclare under our sole responsibility that our productSony Ericsson type AAC-1052091-BVand in combination with our accessories, to which this declaration relates is in conformity with the appropriate standards EN 301 511:V9.0.2, EN 300 328:V1.7.1, EN 301 489-7:V1.3.1, EN 301 489-17:V1.2.1 and EN 60950-1:2006, following the provisions of, Radio Equipment and Telecommunication Terminal Equipment Directive 1999/5/EC.

A ti mu awọn ibeere Ilana ti R&TTE šẹ (1999/5/EC).

FCC StatementThis device complies with Part 15 of the FCC rules. Operation is subject to the following two conditions: (1) This device may not cause harmful interference, and (2) This device must accept any interference received, including interference that may cause undesired operation.Any change or modification not expressly approved by Sony Ericsson may void the user’s authority to operate the equipment. This equipment has been tested and found to comply with the limits for a Class B digital device, pursuant to Part 15 of the FCC Rules. These limits are designed to provide reasonable protection against harmful interference in a residential installation. This equipment generates, uses and can radiate radio frequency energy and, if not installed and used in accordance with the instructions, may cause harmful interference to radio communications. However, there is no guarantee that interference will not occur in a particular installation. If this equipment does cause harmful interference to radio or television reception, which can be determined by turning the equipment off and on, the user is encouraged to try to correct the interference by one or more of the following measures:- Reorient or relocate the receiving antenna.- Increase the separation between the equipment and receiver.- Connect the equipment into an outlet on a circuit different from that to which the receiver is connected.- Consult the dealer or an experienced radio/TV technician for help.

Lund, March 2008

Shoji Nemoto, Head of Product Business Unit GSM/UMTS

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 41: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

41

Industry Canada StatementThis device complies with RSS-210 of Industry Canada. Operation is subject to the following two conditions: (1) this device may not cause interference, and (2) this device must accept any interference, including interference that may cause undesired operation of the device. This Class B digital apparatus complies with Canadian ICES-003. Cet appareil numérique de la classe B est conforme à la norme NMB-003 du Canada.Sony Ericsson W302GSM 850/900/1800/1900Itọsọna olumulo yi jẹ atẹjade nipasẹ Sony Ericsson Mobile Communications AB tabi ajọ agbegbe to somọ, laisi eyikeyi atilẹyin ọja. Awọn didara si jẹ iyipada si itọsona olumulo yi fi agbara muse pẹlu ašiše, laisi fun alaye to wa, tabi awọn didara si awọn eto ati/tabi ẹrọ, le jẹ šiše nipasẹ Sony Ericsson Mobile Communications AB nigbakugba ati laisi akiyesi. Iru ayipada yoo, sibẹsibẹ, Šee dapọ si iwe titun Itọsọna olumulo yi.Gbogbo ẹtọ ti wa ni ipamọ.© Sony Ericsson Mobile Communications AB, 2008Jọwọ še akiyesi: Diẹ ninu awọn isẹ Itọsọna olumulo ko ni atilẹyin fun gbogbo awọn nẹtiwọki. Eleyi na kan Nọmba GSM Pajawiri Ilu okeere 112. Jọwọ kan si onišẹ nẹtiwọki tabi olupese išẹ rẹ ti o ba nše iyemeji boya o le lo išẹ kan tabi rara. Jọwọ ka Alaye pataki šaaju ki o to lo foonu alagbeka rẹ. Gbogbo awọn aworan apejuwe wa fun aworan apejuwe nikan o le ma še dede foonu gangan.Foonu alagbeka rẹ ni agbara lati gba lati ayelujara, tọju kosi firanšẹ siwaju akoonu, fun apeerẹ. awọn ohun orin ipe. Lilo iru akoonu bẹ le ni ihamọ tabi awọn ẹtọ ẹnikẹta, pẹlu šugbọn ko ni opin si hihamọ labẹ awọn ofin didakọ to wulo. Iwọ, ni kii še Sony Ericsson, ni o šee igbọkanle lodidi fun akoonu afikun ti o gba wọle lati ayelujara si tabi firanšẹ siwaju lati foonu alagbeka rẹ. Šaaju si lilo akoonu afikun eyikeyi, jọwọ mọ daju wipe ipinnu lilo rẹ ni iwe-ašẹ daradara tabi bibẹkọ ti gba ašẹ. Sony Ericsson ko še onigbọwọ išẹdede, iyege tabi didara eyikeyi afikun akoonu tabi akoonu eyikeyi miiran ti ẹnikẹta. Laisi alaye-pipe njẹ Sony Ericsson duro ni ọnakọna fun aibojumu lilo akoonu afikun tabi akoonu ẹnikẹta miiran. Išẹ ọna ẹrọ Ọrọ Asọtẹlẹ jẹ lilo labẹ iwe-ašẹ lati Zi Corporation. Samisi ọrọ ati awọn aami Bluetooth ti ni oniwun nipasẹ Bluetooth SIG, Inc. ati lilo eyikeyi iru awọn aami bẹ nipasẹ Sony Ericsson wa labẹ iwe ašẹ. Ti ni iwe-ašẹ išẹ ọna ayipada ohun MPEG Layer-3 lati ọdọ Fraunhofer IIS ati Thomson. Microsoft jẹ aami-išowo ti a forukọsilẹ ti Microsoft Corporation ni Orilẹ Amẹrika ati/tabi awọn orilẹ-ede miiran.

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.

Page 42: W302 UG YO 1209 9725 3 - Sony Mobile€¦ · Tẹ bọtini kan lati tan imọlẹ si iboju ki o wo ipo gbigba agbara. 2 Lati yọọ šaja kuro, tẹ pulọọgi si ọna oke. ...

Sony Ericsson Mobile Communications ABSE-221 88 Lund, Sweden

www.sonyericsson.com

1209-9725.3

Printed in Country

This is the Internet version of the User guide. © Print only for private use.