Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re,...

27
Ibere ijiya eniyan Bibeli fun awon omode

Transcript of Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re,...

Page 1: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Ibere ijiya eniyan

Bibeli fun awon omode

Page 2: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Ikosile gba owo: Edward Hughes

Ayaworan: Byron Unger; Lazarus

Olu’lo: M. Maillot; Tammy S.

Atunmo ede: Oluwashina Oluwadimu

Alakoso: Bible for Childrenwww.M1914.org

©2013 Bible for Children, Inc.Iwe ase: Oni ase lati se atunko tabi attune itan yi,

niwon igba ti o ko so di owo.

Page 3: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

OLORUN DA OHUN GBOGBO! Nigbati Olorun da okunrin akoko, Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe

won si ngboran si Olorun won si ngbadun iwapelu

re titi ojo kan …

Page 4: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

“Looto li Olorunni ki emase je ninu

gbogbo igi?” Ejo bi Efa. “Ale je ninu gbogbo igi eleso

ayafi okan,” Odaa lohun. “Sugbon bi

aba je tabi fowokan eso yen, awa yioku.” “Enyin koni

ku,” Ejo wi.

Page 5: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

“Enyin yio dabi Olorun.” Efa fe eso igi na. Ogbo si ejo lenu osi je eso na.

Page 6: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Lehin igbati Efa saigboran so Olorun, Omu Adamu lati je eso na. Adamu ibati so wipe, “Rara O! Emi ki yio saigboran si oro Olorun.”

Page 7: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Nigbati Adamu ati Efa se, won ri wipe awon wan i ihoho. Won mu ewe lati fi bo ihoho won, won fi ara pamo kuro niwaju Olorun.

Page 8: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Li asale, Olorun wa sinu ogba. O mo ohun ti Adamu ati Efa tise. Adamu tie bi si Efa. Efa pelu ti ebi si ejo. Olorun wipe, “Egun ni fun ejo. Obirin yio ni ijiya nigbati o ba bi omo.”

Page 9: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

“Adamu, nitoripe o se, afi ile bu fun o pelu egun ati osusu. Iwo yio jiya pelu oogun ki oto jeun ojo.”

Page 10: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Olorun mu Adamu ati Efa kuro ninu ogba didara. Nitoriwipe won se, aya won kuro lodo Olorun alaaye!

Page 11: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Olorun da ida ina lati le won jade. Olorun se aso eleran igbe fun Adamu ati Efa. Nibo li Olorun timu eran ara eranko wa?

Page 12: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Laipe ojo, Adamu ati Efa bimo. Omokunrin akoko, Kaini, je agbe. Omokunrin ekeji, Abeli, je oluso agutan.

Page 13: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Li ojo kan Kaini mu ewebe wa fun Olorun gegebi ebun. Abeli pelu mu awon agutan to joju wa fun Olorun gegebi ebun. Olorun tewo gba ebun Abeli.

Page 14: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Olorun ko tewogba ebun Kaini. Kaini banuje. Sugbon Olorun wipe, “Bi iwo base rere, a o ni gba o bi?”

Page 15: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Ibinu kaini ko kuro. Lehin igbakan o pa Abeli ninu oko- osi paa.

Page 16: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Olorun wi fun Kaini pe. “Nibo li Abeli arakunrin re wa?” “Emi komo,” Kaini pa iro. “Emi je oluso agutan re bi?” Olorun fi iya je Kaini, kose agbe mo, o so di alarinkiri.

Page 17: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Kaini lo kuro niwaju OLUWA. Omu omobinrin Adamu li aya. Won si li ebi.

Page 18: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Laipe, awon omo-omo ati omo-omo-omo kaini kun ilu ti o ko.

Page 19: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Sugbon, awon iran Adamu ati Efa dagba ni kiakia. Li ojo wonni, awon eniyan gbe pe ju ojo oni lo.

Page 20: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Nigbat abi Seti, Efa wipe, “oLorun fi Seti fun mi lati ropo Abeli.” Seti je eniti o beru Olorun osi gbe igbe aye egberun din adorundineji. Oni omo pupo.

Page 21: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Ninu aiye, awon eniyan buru si bi iran kan se ntele omiran. Nigbehin, Olorun pinu lat pa eniyan run ati ...

Page 22: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

… awon eranko ati eiye oju orun. Inu Olorun kodun nitori oda eniyan. Sugbon eniyan kan te Olorun lorun ...

Page 23: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Eni na ni Noa. Iran Seti, Noa je olododo ati olooto. O rin pelu Olorun.

Page 24: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

O ko awon omokunrin re meta lati gboran si Olorun. Nisiyii Olorun pinu lati lo Noa li ona ti o dara!

Page 25: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Ibere ijiya eniyan

Itan lati inu oro Olorun, Bibeli

lari ka ninu

Genesisi ori keta si ori kefa (3-6)

“Iwole oro re funwa ni imole.”Orin Dafidi 119:130

Page 26: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Opin

Page 27: Ibere ijiya eniyan - Bible for Children · 2016-01-19 · Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu . aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe . ... Orin Dafidi 119:130. Opin. Itan Bibeli yii so fun

Itan Bibeli yii so fun wa nipa Olorun iyanu wa t’oda wa ti osi fe ki amo ohun.

Olorun mo wipe ati se ohun ibi, ti ope ni ese. Iku ni ere ese, sugbon Olorun feran re tobe ge tofi omo re kan soso, Jesu, ranse lati ku lori igi agbelebu ki osi jiya fun ese re. Jesu si pada wa si aaye osi losi ile l’orun! Bi o ba gbagbo ninu Jesu ti osi toro idariji ese re, Yi o se eyi! Yi o si wa

gbe ninu re nisisiyi, iwo yio si gbe pelu re lailai.

Bi o ba gbagbo wipe otito ni eyi, so fun Olorun wipe:Jesu mi owon, Mo gbagbo wipe ire ni Olorun, o di eniyan

lati ku fun ese mi, osi wa laaye sibe. Jowo wa sinu aye mi ki osi dari ese mi jimi, ki emi ki oni aye otun nisisiyi, ati ni ojo kan ki emi kole wa pelu re titi lai. Ranmilowo lati gbo

tire ati lati je omo o re. Amin.

Ka Bibeli re ki osi ba Olorun soro lojumo! Johannu ori keta ese kerindinlogun.